Fri Nov 08 2019 10:35:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-08 10:35:36 +01:00
commit 2aaf1d45f7
27 changed files with 82 additions and 0 deletions

1
01/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 1 Símónì Pétérù, ẹrú àti àpóstélì Jésù Krístì, sí àwọn tọ́ ti gba ìgbàgbọ́ iyebíye tí àwa náà ti gbà, ìgbàgbọ nínú òdodo Ọlórun àti Olùgbàlà wá Jésù Krístì \v 2 Kí Oreọ̀fẹ́ àti àláfíà máa pọ̀ si ní ìwọ̀n ọgbọ́n Ọlórun àti ti Jésù Olúwa wá.

1
01/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Gbogbo ohun tí óníṣe pẹ̀lú agbára àtòkèwá fún ìyè àti ìwàbíi-Ọlórun lati fi fún wa nípa ọgbọn Ọlórun, Ẹni tí óti pèwá nípa ògo àti ìwà rerẹ̀ Rẹ̀. \v 4 Nípa ìwọ̀nyí, Óti fún wa ní ìlérí ńlá àti èyítí óse iyebíye, kí ìwọ leè jẹ́ alábàápín nínú-un ara àtòkèwá, bí ó ṣe ń yọ kúrò nínu ìbàjẹ́ tí ó wà nínu ayé nítorí àwọn ìfẹ́-ọkàn búburú.

1
01/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Fún ìdí èyí, sa ipá rẹ láti fikún ìwà-rere nípa ìgbàgbọ rẹ, àti nípa ìwà-rere, ìmọ̀. \v 6 Nípa òye rẹ, fikún ìwà ìkóra ẹni-ní-ìjánu, àti nípa ìwà ìkóra ẹni-ní-ìjánu rẹ, fikún ìpamọ́ra, àti nípa ìpamọ́ra rẹ, fikún ìwà bí Ọlórun. \v 7 Nípa ìwà bí Ọlórun rẹ, fikún ìfé-ará, àti nípa ìfẹ́-ará rẹ, fikún ìfẹ́.

1
01/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Bí àwọn ǹkan wọ̀nyín báwà nínú-ùn rẹ, tí wọ́n sì-ń dàgbà nínú rẹ, o kò ní jẹ́ àgàn tàbí àláìléso ní ti ìmọ̀ Olúwa wa Jésù Krístì. \v 9 Sùgbọ́n ẹnikẹ́ni tóbá jẹ́ aláìní àwọn ǹkan wọ̀nyí rí oun tó súnmọ́ọ nìkan; ó jẹ́ afọ́jú. Ó ti gbàgbé ìwẹ̀nùmó kúrò nínú ẹ̀sẹ̀ àtijọ́ rẹ̀.

1
01/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Nítorínà, ará, sá ipáàrẹ láti jẹ́ kí ìpè àti yíyàn rẹ dá ọ lójú. Bí o bá ṣe àwọn ǹkan wọ̀nyín, o kò ní subú. \v 11 Ní ọ̀nà yí wíwọlé sí ìjọba ayérayé ti Olúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Krístì ní a ó fifún yín lọ́pọ̀lọpọ̀.

1
01/12.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 12 Nítorínà èmi yóò ṣetán nígbàgbogbo láti máarán-yín létí àwọn ǹkan wọ̀nyí, bótilẹ̀jẹ́pé ẹ mọ̀ wọ́n, àti bótilẹ̀jẹ́pé ẹ ti dàgbà nínú òtítọ́ nísisìnyí. \v 13 Mo lé rò pé ó tọ́ fún mi láti ru yín sókè pẹ̀lú ìrántí nípa àwọn ǹkan wọ̀nyí, ní ìwọ̀n ìgbà tí mo wà nínu àgọ́ yìí. \v 14 Nítorí mo mọ̀ pé láìpẹ́, èmi yóò yọ àgọ́ mí, bí Olúwa wa Jésù Krístì tí fí hàn mí. \v 15 Èmi yóò sa ipá mi fún-un yín láti lè ma rántí àwọn ǹkan wọ̀nyí lẹ́yìn tí mo bá lọ tán.

1
01/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Nítorí a kò tẹ̀lé pẹ̀lú àkàyé àwọn àròsọ tí a dá nígbàtí asọ fún yín nípa agbára àti ìrísí Olúwa wa Jésù Krístì. Dípò, àwa jẹ́ ẹlẹ́rìí ọláńlá rẹ̀. \v 17 Nítorí ó gbà látọ̀dọ Ọlórun Bàbá, ọlá àti ògo nígbàtí ohùn kan tọ̀ọ́ wá nípa ọlá Ògo tó wípé, ''Èyí ni Ọmọ mi, Ẹni tí mo fẹ́, ẹni tí inú-ùn mí dùn sí gidgidi'' . \v 18 Agbọ́ ohùn tó jáde látọ̀run wá, nígbàtí a wà pẹ̀lú rẹ̀ lórí òkè mímọ́.

BIN
01/19.txt Normal file

Binary file not shown.

1
02/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 1 Àwọn wòlíì èké tọ àwọn ènìyàn wá, àti àwon olùkọ́ èké yóò sì tọ̀ yín wá.Wọn ó fi ìkọ̀kọ̀ mú ìparun èké pẹ̀lú wọn wá, wọn yó sì sẹ́ olúwa wọn eni tí ó ràn wọ́n. Wọ́n sì mú ìparun wá sórí ara wọn. \v 2 Púpọ̀ ni yóó tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ wọn, àti nípa wọn ọ̀nà òtítọ́ yóò sì di búburú. \v 3 Pẹ̀lú wòbìà wọ́n yò jẹ èrè lára yín pẹ̀lú ọ̀rọ́ ẹ̀tàn. Ìdálẹ́bi wọn kò kín pẹ́ títí; ìparun wọn kò kín-ń sùn.

1
02/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 Nítorí Ọlọ́run kò dá àwọn áńgẹ́lì tó ṣẹ̀ láre. Dípò ó fi wọ́n lé Tátárúsì lọ́wọ́ láti wà ní ìpamọ́ ẹ̀wọ̀n tí òkùnkùn-abẹ títí di ìdájọ́. \v 5 Bákanáà, kò dá àwọn ayé àtijọ́ láre. Dípò, ó pa Nóàh mọ́, tó jẹ́ olùpolongo òdodo, pẹ̀lú àwọn méje míì, nígbàtí ó mú ìkun omi wá sóríi ayé àwọn aláìwà bíi Ọlọ́run. \v 6 Ọlọ́run túnbọ̀ dín ìlú Sódọ́mù àti Gòmórrà kú sí ẹ́rú ósìi dá wọn lẹ́bi ìparun, gẹ́gẹ́ bi àpẹẹrẹ oun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwon aláíwà bíi Ọlọ́run.

1
02/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 Ṣùgbọ́n fun Lóòtì olódodo, tí wọ́n nilára pẹ̀lu ìwà àwọn ènìyàn arufin nínu ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́, Ọlọ́run kóoyọ. \v 8 Fún ọkùnrin olódodo náà, tí ńgbé ní àrin wọn ní ọjọ́ dé ọjọ́, la pọ́n lójú ní ọkàn òdodo rẹ̀ nítorí ǹkan tí ó rí àti tí ó gbọ́. \v 9 Olúwa mọ bí ó tín yọ àwon ènìyàn bí Ọlọ́run kúrò nínu ìdánwò, àti láti mú àwọn ènìyàn aláìsòdodo fún ìjìyà ní ọjọ́ ìdájọ́.

1
02/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Èyíì pàápàá jẹ́ òtọ́ọ́ fún àwọn tí ó ńtẹ́sìwájú nínú ìpòngbẹ búburú ti ara àti tí ngán àsẹ. Wọ́n jẹ́ àlágídí àti aládàámọ̀. Ẹ̀rù kò bà wọ́n láti lòdì sí àwọn ológo. \v 11 Àwon áńgẹ́lì ní okun àti agbára tí ó tóbi, ṣùgbọ́n wọn kìí nmú ìdájọ́ àbùkù wọn wá sí ọ̀dọ Ọlọ́run.

1
02/12.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 12 Ṣùgbọ́n àwon eranko àláìlọ́kan yìí wà fún mimu àti píparun.Wọ́n kò mọ oun tí wọ́n ń kàn lábùkù. A ó pawọ́n run. \v 13 Wọ́n yóò gba èrè iṣẹ́ ibi wọn. Wọ́n ró wípé ìgbádùn ní ọjọ́ jẹ́ ìdùnnú. Wọ́n ní ìdọ̀tí àti àbàwọ́n. Wọ́n máa ń gbádùn àwọn ìwà ẹ̀tàn wọn nígbàtí wọ́n bá ń jẹ àsè pẹ̀lú yín. \v 14 Wọ́n ní ojú tí ó kún fún panságà obìnrin; wọn kìí ní ìtẹ́lọ́rùn pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ̀. Wọ́n tan ọ́kàn tí kò dúró sínu iṣẹ́ ibi, àti ọkàn wọn ní atikó nínú ojúkókòrò.Wọ́n jẹ́ ọmọ-ègún!

1
02/15.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 15 Wọ́n ti kọ ọ̀nà òtítọ́ sílẹ̀. Wọ́n ti sọnù, wọ́n sì ti tẹ̀lé ọ̀nà Bálámù ọmọ Bósórì, tó fé láti gba owó fún àiṣòdodo. \v 16 Ṣùgbọ́n ó gba ìbáwí fún ìrékọjá rẹ̀. Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ odi kan tó ń sọ̀rọ̀ ní ohùn ènìyàn da asiwèrè wòlíì dúró.

1
02/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 Àwọn ọkùnrin yìí dàbí òrísun tí kó lómi. Wọ́n dàbí àwọsánmà tí ìjì wọ́ lọ. Òkùnkùn tó nípọn wà ní ìpámọ́ fún wọn. \v 18 Wọ́n sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìyájú asán. Wọ́n tan àwọn ènìyàn pẹ̀lú ìfẹ́kùfẹ́ tara. Wọ́n tan àwọn ènìyàn to ngbìyànjú láti sá kúrò lọ́dọ̀ `awon tó ngbé nínu àsíse. \v 19 Wọ́n sèlérí òmìnira fún wọn, ṣùgbọ́n àwọn gan fún ra wọn jẹ́ ẹrú-ìbàjẹ́. Nítorí ènìyàn jẹ́ ẹrú sí ohunkóhun tó bá borí rẹ̀.

1
02/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 20 Ẹnikẹ́ni tó bá yọ nínú àìmọ́ ayé nípa ti ìmọ̀ Olúwa ati Olùgbàlà Jésù Krístì, tí ó sìí pàdà sí àwọn àìmọ́ yìí, ìpìnlẹ̀ kẹhìn ti di búburú fún wọn ju ti ìpìnlẹ̀ àkọ́kọ́ lọ. \v 21 Yó tìi dára fún wọn láti má mọ̀ọ ọ̀na òdodo ju kí wọ́n mòọ́ kí wọ́n sìi yà kúrò nínú àsẹ mímọ́ tí a fifún wọn. \v 22 . Òwe yìí jẹ́ òtítọ́ fún wọn: Ajá pàdà sí èébì rẹ̀. Ẹlẹ́dẹ̀ mímọ́ pàdà sí àbàtà.

1
03/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 1 Nísinsìnyí, mò ń kọ ìwé síiyín, ará, ìwé kejí yii gẹ́gẹ́ bíi ìrántí làti rú ọkàn òdodo yín sókè, \v 2 kí ẹ̀yin bà lè rántí ọ̀rọ̀ tí a sọ látẹ̀yìn wá nípa àwọn wòlíì mímọ́ àti àṣẹ tí Olúwa àti Olùgbàlà tí a fún wa nípa àwọn àpóstélì yín.

1
03/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Àkọ́kọ́ ẹmọ èyí, wípé àwọn olùkẹ́gàn yóò wá ní ọjọ ìkẹhìn. Wọ́n yóò kẹ́gàn àti tẹ̀síwájú nínú ìfẹ́ ọkàn wọn. \v 4 Wọn yóò wípé, Ìlérí ìpadàbọ̀ rẹ̀ dà? Nígbàtí àwọn bàbá wa sún orun, gbogbo ǹkan tí wà bẹ́ẹ̀, láti ìbẹ̀rẹ̀ ísẹ̀dá.

1
03/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Tìfẹ́tìfẹ́ wọ́n gbàgbé wípé ọ̀run àti ayé tẹ̀lẹ̀ láti inú omi àti nípa omi tipẹ́tipẹ́ nípa àsẹ Ọlọ́run , \v 6 àti nípa àwọn wọ̀nyí, ayé ìgbànáà dí ìparun, pẹ̀lú ìkún omi. \v 7 Ṣùgbọ́n nísinsìnyí àwọn ọ̀run àti ayé wà ní ìpamọ́ fún iná nípa òfin kanáà. Wọ́n wà ni ìpamọ́ fún ọjọ́ ìdájọ́ àti ìparun tì àwọn ènìyàn aláíwà bi Ọlórun.

1
03/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Kò gbọdò kúrò ní àkíyèsí rẹ́, ará, wípé ọjọ́ kan pẹ̀lú Olúwa dàbíi ẹgbẹ̀rún ọdún, ẹgbẹ̀rún ọdún sí dàbíi ọjọ́ kan. \v 9 Olúwa kìí jáfara sí ìlérí rẹ̀, bí àwọn ǹkan ṣe ka àìjáfara sí. Dípò, ó ní sùrúù síi yín. Kò wú nínu ìfẹ́ rẹ̀ láti jẹ́ kí ìkankan nínú yín parun, ṣùgbọ́n kí gbogbo ènìyàn fàyè gba fún ìrònúpìwàdà.

1
03/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Síbẹ̀síbẹ̀, ọjọ́ Olúwa yóò de bí olè: Àwọn ọ̀run yóò kọjá lọ pẹ̀lú ariwo ńlá. Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run yóò jóná pẹ̀lú iná, àti ayé àti isẹ́ rẹ̀ yóò di ífihàn.

1
03/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Nígbàti ósì ti jẹ́ pe àwọn ǹkan wọ̀n yìí ni a ó parun ní ọ̀nà yí. Irú ènìyàn wo ni ẹ ó jẹ̀ẹ́? Kí ẹ gbé ìgbéayé mímọ àti ìgbéayé ìwà bíi Ọlọ́run. \v 12 Kí ẹ palẹ̀mọ́ kí ẹ sì ṣọ́na fún bíbọ̀ ọjọ́ Olúwa. Ní ọjọ́ nà, àwọn ọ̀run yóò di píparun pẹ̀lú iná, àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀ ni a ó yọ́ pẹ̀lú ooru gbígbónán girigiri. \v 13 Ṣùgbọ́n nípa ìlérí Rẹ̀ àwa n dúró de ọ̀run titun àti ayé titun, níbití òdodo yóò gbé wà.

1
03/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Nítorínà, olùfẹ́, nígbàtí ẹ sì ń retí nkán wọ̀nyí, ẹ sa ipá yín láti wà nì aláìlábàwọ́n àti aláìlábùkù ní iwájú Rẹ̀, ní àláfíà. \v 15 Bẹ́ẹ̀ni kí ẹ rí sùúrù Olúwa wa sí ìgbàlà, bí olùfẹ́ arákùnrin Pọ́ọ̀lù ti kọ̀wé síi yín, bíi ọgbọ́n tí a fi fún-un. \v 16 Pọ́ọ̀lù sọ gbogbo ǹkan wọ̀nyí nínú àwọn lẹ́ẹ̀ta rẹ̀, nínú èyí tí àwọn ohun kọ̀kan ṣòro láti nì òye rẹ̀. Ọkùnrin aláímọ̀kan àti oníṣégeṣège túmọ̀ àwọn ǹkan wọ̀nyí, bí wọ́n ṣeṣe àwọn ìwé mímọ́ míràn, sí ìparun ti wọn.

1
03/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 Nítorínà, ará, níwọ̀n tí ẹmọ àwọn ǹkan wọ̀nyí, ẹ pa ara yín mọ́ kí ẹ má ba lè sọnù pẹ̀lú ẹ̀tàn àwọn ènìyàn aláípòfinmọ́ kí o sìi pàdánù òtítọ́ rẹ. \v 18 Ṣùgbọń ẹ dàgbà nínu ore-ọ̀fẹ́ àti ìmọ̀ Ọlúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Krístì. Kí ògo kó jẹ́ tí Rẹ̀ nísinsìnyí àti títí láíláí. Àmín

29
LICENSE.md Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
# License
## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0)
This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/.
### You are free to:
* **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format
* **Adapt** — remix, transform, and build upon the material
for any purpose, even commercially.
The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms.
### Under the following conditions:
* **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work.
* **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original.
**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits.
### Notices:
You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation.
No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material.
This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/).

1
front/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
2 Peter

29
manifest.json Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
{
"package_version": 6,
"format": "usfm",
"generator": {
"name": "ts-desktop",
"build": "132"
},
"target_language": {
"id": "yo",
"name": "Yorùbá",
"direction": "ltr"
},
"project": {
"id": "2pe",
"name": "2 Peter"
},
"type": {
"id": "text",
"name": "Text"
},
"resource": {
"id": "ulb",
"name": "Unlocked Literal Bible"
},
"source_translations": [],
"parent_draft": {},
"translators": [],
"finished_chunks": []
}