adesinaabegunde_yo_2pe_text.../03/08.txt

1 line
449 B
Plaintext

\v 8 Kò gbọdò kúrò ní àkíyèsí rẹ́, ará, wípé ọjọ́ kan pẹ̀lú Olúwa dàbíi ẹgbẹ̀rún ọdún, ẹgbẹ̀rún ọdún sí dàbíi ọjọ́ kan. \v 9 Olúwa kìí jáfara sí ìlérí rẹ̀, bí àwọn ǹkan ṣe ka àìjáfara sí. Dípò, ó ní sùrúù síi yín. Kò wú nínu ìfẹ́ rẹ̀ láti jẹ́ kí ìkankan nínú yín parun, ṣùgbọ́n kí gbogbo ènìyàn fàyè gba fún ìrònúpìwàdà.