adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/12.txt

1 line
685 B
Plaintext

\v 12 Ṣùgbọ́n àwon eranko àláìlọ́kan yìí wà fún mimu àti píparun.Wọ́n kò mọ oun tí wọ́n ń kàn lábùkù. A ó pawọ́n run. \v 13 Wọ́n yóò gba èrè iṣẹ́ ibi wọn. Wọ́n ró wípé ìgbádùn ní ọjọ́ jẹ́ ìdùnnú. Wọ́n ní ìdọ̀tí àti àbàwọ́n. Wọ́n máa ń gbádùn àwọn ìwà ẹ̀tàn wọn nígbàtí wọ́n bá ń jẹ àsè pẹ̀lú yín. \v 14 Wọ́n ní ojú tí ó kún fún panságà obìnrin; wọn kìí ní ìtẹ́lọ́rùn pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ̀. Wọ́n tan ọ́kàn tí kò dúró sínu iṣẹ́ ibi, àti ọkàn wọn ní atikó nínú ojúkókòrò.Wọ́n jẹ́ ọmọ-ègún!