1 line
894 B
Plaintext
1 line
894 B
Plaintext
\v 19 A ní ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí ó dájú. Ẹ ṣe dárádára láti ṣe àkíyèsí rẹ̀. Ó dàbí àtùpà tín taná nínú òkùnkùn títí di òwúrọ̀ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ gbésékè nínu ọkàn rẹ \v 20 Ẹ kọ́kọ́ mọ èyí, wípé kòsí ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tó jẹ́ tí ìtumọ̀ ènìyàn kan. \v 21 Nítorí kòsí àsọtẹ́lẹ̀ tó wá nípa ìfẹ́ ènìyàn. Dípò, àwọn ènìyàn tí Ẹ̀mí Mímọ́ tó sọ jáde látọ̀dọ Ọlọ́run. |