adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/10.txt

1 line
408 B
Plaintext

\v 10 Èyíì pàápàá jẹ́ òtọ́ọ́ fún àwọn tí ó ńtẹ́sìwájú nínú ìpòngbẹ búburú ti ara àti tí ngán àsẹ. Wọ́n jẹ́ àlágídí àti aládàámọ̀. Ẹ̀rù kò bà wọ́n láti lòdì sí àwọn ológo. \v 11 Àwon áńgẹ́lì ní okun àti agbára tí ó tóbi, ṣùgbọ́n wọn kìí nmú ìdájọ́ àbùkù wọn wá sí ọ̀dọ Ọlọ́run.