adesinaabegunde_yo_2pe_text.../03/11.txt

1 line
588 B
Plaintext

\v 11 Nígbàti ósì ti jẹ́ pe àwọn ǹkan wọ̀n yìí ni a ó parun ní ọ̀nà yí. Irú ènìyàn wo ni ẹ ó jẹ̀ẹ́? Kí ẹ gbé ìgbéayé mímọ àti ìgbéayé ìwà bíi Ọlọ́run. \v 12 Kí ẹ palẹ̀mọ́ kí ẹ sì ṣọ́na fún bíbọ̀ ọjọ́ Olúwa. Ní ọjọ́ nà, àwọn ọ̀run yóò di píparun pẹ̀lú iná, àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀ ni a ó yọ́ pẹ̀lú ooru gbígbónán girigiri. \v 13 Ṣùgbọ́n nípa ìlérí Rẹ̀ àwa n dúró de ọ̀run titun àti ayé titun, níbití òdodo yóò gbé wà.