adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/15.txt

1 line
347 B
Plaintext

\v 15 Wọ́n ti kọ ọ̀nà òtítọ́ sílẹ̀. Wọ́n ti sọnù, wọ́n sì ti tẹ̀lé ọ̀nà Bálámù ọmọ Bósórì, tó fé láti gba owó fún àiṣòdodo. \v 16 Ṣùgbọ́n ó gba ìbáwí fún ìrékọjá rẹ̀. Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ odi kan tó ń sọ̀rọ̀ ní ohùn ènìyàn da asiwèrè wòlíì dúró.