adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/04.txt

1 line
660 B
Plaintext

\v 4 Nítorí Ọlọ́run kò dá àwọn áńgẹ́lì tó ṣẹ̀ láre. Dípò ó fi wọ́n lé Tátárúsì lọ́wọ́ láti wà ní ìpamọ́ ẹ̀wọ̀n tí òkùnkùn-abẹ títí di ìdájọ́. \v 5 Bákanáà, kò dá àwọn ayé àtijọ́ láre. Dípò, ó pa Nóàh mọ́, tó jẹ́ olùpolongo òdodo, pẹ̀lú àwọn méje míì, nígbàtí ó mú ìkun omi wá sóríi ayé àwọn aláìwà bíi Ọlọ́run. \v 6 Ọlọ́run túnbọ̀ dín ìlú Sódọ́mù àti Gòmórrà kú sí ẹ́rú ósìi dá wọn lẹ́bi ìparun, gẹ́gẹ́ bi àpẹẹrẹ oun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwon aláíwà bíi Ọlọ́run.