adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/17.txt

1 line
579 B
Plaintext

\v 17 Àwọn ọkùnrin yìí dàbí òrísun tí kó lómi. Wọ́n dàbí àwọsánmà tí ìjì wọ́ lọ. Òkùnkùn tó nípọn wà ní ìpámọ́ fún wọn. \v 18 Wọ́n sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìyájú asán. Wọ́n tan àwọn ènìyàn pẹ̀lú ìfẹ́kùfẹ́ tara. Wọ́n tan àwọn ènìyàn to ngbìyànjú láti sá kúrò lọ́dọ̀ `awon tó ngbé nínu àsíse. \v 19 Wọ́n sèlérí òmìnira fún wọn, ṣùgbọ́n àwọn gan fún ra wọn jẹ́ ẹrú-ìbàjẹ́. Nítorí ènìyàn jẹ́ ẹrú sí ohunkóhun tó bá borí rẹ̀.