adesinaabegunde_yo_2pe_text.../01/16.txt

1 line
750 B
Plaintext

\v 16 Nítorí a kò tẹ̀lé pẹ̀lú àkàyé àwọn àròsọ tí a dá nígbàtí asọ fún yín nípa agbára àti ìrísí Olúwa wa Jésù Krístì. Dípò, àwa jẹ́ ẹlẹ́rìí ọláńlá rẹ̀. \v 17 Nítorí ó gbà látọ̀dọ Ọlórun Bàbá, ọlá àti ògo nígbàtí ohùn kan tọ̀ọ́ wá nípa ọlá Ògo tó wípé, ''Èyí ni Ọmọ mi, Ẹni tí mo fẹ́, ẹni tí inú-ùn mí dùn sí gidgidi'' . \v 18 Agbọ́ ohùn tó jáde látọ̀run wá, nígbàtí a wà pẹ̀lú rẹ̀ lórí òkè mímọ́.