Thu Jan 14 2021 15:48:40 GMT-0500 (EST)

This commit is contained in:
scunningham 2021-01-14 15:48:40 -05:00
commit 76d35dd279
23 changed files with 110 additions and 0 deletions

1
01/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 1 \v 1 Pọ́ọ̀lù, Sílfánù, àti Tìmótíù, sí ìjọ Tẹsalóníkà nínú Ọlọ́run Bàbá wa àti Olúwa Jésù Kristì. \v 2 Kí ore-ọ̀fẹ́ àti àláfíà jẹ́ ti yín láti ọ̀dọ Olọ́run Bàbá wa àti Olúwa Jésù Kristì.

1
01/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 A gbọdọ̀ máa fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nígbàgbogbo fún yín, ará. Nítorí èyí ni ó tọ̀nà, nítorípé ìgbàgbọ́ yín ń dàgbà púpọ̀púpọ̀ àti ìfẹ́ olúkúlùkù sí ara wọn ń pọ̀si. \v 4 Nítorí náà ni àwa tìkarawa fi ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìgboyà nípa yín láàrin ìjọ Ọlọ́run. À ń sọ̀rọ̀ sùúrù àti ìgbàgbọ́ nínú gbogbo inúnibíni yín. À ń sọ̀rọ̀ nípa wàhálà tí ẹ faradà. \v 5 Èyí ni àpẹẹrẹ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run. Ère rẹ̀ ni pé a ó kà yín yẹ ní ìjọba Ọlọ́run nínú èyí tí ẹ jìyà lé lórí.

1
01/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Òdodo ni fún Ọlọ́run láti dá ìpọ́njú padà sì ọ̀dọ̀ àwọn tí ó ń pọ̀n yín lójú, \v 7 Àti ìtura fún ẹ̀yin tí a pọ́n lójú pẹ̀lú wa. Yóò se èyí nígbà ìfarahàn Jésù Olúwa láti Ọrun wá pẹ̀lú àwọn ángẹ́lì alágbára Rẹ̀. \v 8 Nínú ọ̀wọ́ iná ni yóò gba ẹ̀san lára àwọn tí kò mọ Ọlọ́run àti àwọn tí kò gba ìhìnrere Jésù Olúwa wa.

1
01/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Wọn ó jìyà ìparun kúro níwájú Olúwa wa àti nínú ògo agbára Rẹ̀. \v 10 Yóò se èyí nígbà tí ó bá dé ní ọjọ́ náà kí àwọn ènìyàn Rẹ̀ le se é lógo. Nítorí a gba ẹ̀rí wa fun yín gbọ́.

1
01/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Nítorí eyi à ń gbàdúrà nígbàgbogbo fun yín. À gbàdúrà pé Ọlọ́run wa yóò kà yín yẹ fún ìpè yín. Àti pé kí ó le mú gbogbo èrò rere àti gbogbo iṣẹ́ ìgbàgbọ́ ṣẹ pẹ̀lú agbára. \v 12 A gbàdúrà nǹkan wọ̀nyìí kí orúkọ Jésù Olúwa wa le è di gbígbéga nípa yín. A gbàdúrà pé kí ẹ di ẹni íse lógo nípa Rẹ̀, nítorí ore-ọ́fẹ́ Ọlọ́run wa àti Olúwa wa Jésu Kristì.

1
01/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kìnní

1
02/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 2 \v 1 Nísinsìnyí nípa wíwá Olúwa wa Jésù Kristì àti ìpéjọpọ̀ wa láti wà pẹ̀lú Rẹ̀: a bẹ̀ yín, ará, \v 2 pé kí ẹ̀yín kí ó má tètè dààmú tàbí pòrúrú ọkàn, bóyá nípa ti ẹ̀mí, ìwásù, tàbí nípa ìwé bìi láti ọ̀dọ̀ wa wá, fún pé ọjọ́ Olúwa ti dé ná.

1
02/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Ẹ máse jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ lọ́nàkọnà. Nítorípé kí yóò wá bíkòsepé ọjọ́ ìyapa bá dé, tí a ó sì fi ẹlẹ́ṣẹ̀ náà hàn, ọmọ ìparun. \v 4 Òun ni ẹni tí ń lòdì tí ó sì ń gbé ara rẹ̀ ga sí ohungbogbo tí à ń pè ní Ọlọ́run tàbí tí à ń sìn. Ní àbáyọrí pé, ó jòkó nínú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run ó sì tún fi ara rẹ̀ han pé Ọlọ́run ni Òun.

1
02/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Ẹ̀yin kò rántí pé nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín mo sọ nǹkan wọ̀nyìí? \v 6 Nísinsìnyí ẹ̀yín mọ ohun tí ó ń se ìdènà, pé kí á le fihàn ní àkókò tí ó tọ́ nìkan. \v 7 Nítorí ohun ìjìnlẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́, kìki pé ẹnìkan wà tí ó ń se ìdènà fun nísinsìnyí títí a ó fi mu kúrò lọ́nà.

1
02/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Nígbànáà ni a ó fi ẹni ẹ̀ṣẹ̀ náà hàn, ẹnití Jésù Olúwa yóò fi èémí ẹnu rẹ̀ pá. Olúwa yóò mu wá sí asán nípa ìfihàn bíbọ̀ ọ rẹ̀. \v 9 Ọkùnrin ẹni ẹ̀ṣẹ ẹ̀ nì tí yóò wá nítorí iṣẹ́ sátánì pẹ̀lú gbogbo agbára, àmìn, àti èké iṣẹ́ gbogbo, \v 10 àti pẹ̀lú gbogbo ìtànjẹ àìsòdodo. Nǹkan wọ̀nyí yóò wà fún àwọn tí ń sègbé, nítorí tí wọn kò gba ìfẹ́ òtítọ́ tí ó wà fún ìgbàlà wọn.

1
02/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Fún ìdí èyí, Ọlọ́run rán iṣẹ́ ìṣìnà sí wọn kí wọn le gba èké gbọ́. \v 12 Àbáyọrí rẹ̀ ni wípé pé a ó se ìdájọ́ gbogbo wọn, àwọn tí wọn ò gba òtítọ́ ṣùgbọ́n tí wọ́n ní inú dídùn sí àìsòdodo.

1
02/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 Ṣùgbọ́n ó yẹ kí á sábà máa fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nítorí, ẹ̀yin arákùnrin tí olúwa fẹ́. Nítorí Ọlọ́run yànyín sí èso àkọ́soní ìsọdimímọ́ àti ìgbàlà nínú Ẹ̀mí àti ìgbàgbọ́ nínú òtítọ́. \v 14 Èyí ni ohun tí ò pè yín fún pé nípa ìhìnrere wa láti le gba ògo ti Jésù kristì Olúwa wa. \v 15 Nítorínáà, ará, ẹ dúró sinsin. Kí ẹ sì dì ẹ̀kọ́ tí a ti kọ yín mú sinsin, bóyá nípa ọ̀rọ̀ tàbí ìwe wa tí a kọ si yín.

1
02/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Nísinsìnyí kí Olúwa wa Jésù Kristì fún ra rẹ̀, àti Ọlọ́run Bàbá wa tí ó fẹ́ wa tí ó sì tún fún wa ní ìtùnú ayérayé àti ìgboyà rere fún ọjọ́ ìkẹyìn nípa ore-ọ̀fẹ́, \v 17 ìtùnú, kí ó fi ẹṣẹ̀ yín múlẹ̀ nínú gbogbo iṣẹ́ rere àti ọ̀rọ̀.

1
02/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kejì

1
03/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 3 \v 1 Nísinsìnyí ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa pé kí ọ̀rọ̀ Ọlórun tàn jáde ní kánkán kí ó si di ṣíse lògo, gẹ́gẹ́ bí ó tise wà láàrin yín. \v 2 Ẹ máa gbàdúrà pé kí Ọlọ́run gbàwá lọ́wọ̀ àwọn ìkà àti àwọn ènìyàn búburú, nítorí kìí ṣe gbogbo àwọn ènìyàn ni ó gbàgbọ́. \v 3 Ṣùgbọ́n olódodo ni Olúwa, Òhun yóò fi ẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀, yóò sì gbà ọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.

1
03/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 A ní ìgboyà nínú Olúwa nípa yín pé, ẹ̀yin ńṣe, àti pé ẹ̀yin yóò sì tún tẹ̀síwájú láti máa ṣe gẹ́gẹ́ bí a ti paá láṣẹ fun yin. \v 5 Ǹjẹ́, kí Olúwa darí ọkàn yín sí Ìfẹ́ ti Ọlọ́run àti sí ìfaradà ti Krístì.

1
03/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Ǹjẹ́, ará, ní orúkọ Olúwa wa Jésù Krístì, apaá lásẹ fún yín pé, kí ẹ yàgò fún àwọn ará tí ó n se ìmẹ́lẹ́ àti tí wọn kò rìn ní ìbamu pẹ̀lú ìlànà tí ẹti gbà láti ọ̀dọ wa. \v 7 Nítorí ẹ̀yin tìkarayín mọ̀ pe ohun tí ó tọ̀nà ni fún yín láti máa wo àwòkóse wa. Nítorí àwa kò gbé làárín yín bíi ẹnití kò lẹ́kọ̀ọ́. \v 8 Àwa kò jẹ oúnjẹ ẹnikẹ́ni láì san owó. Dípò èyí, àwá ṣisẹ́ ní ọ̀sán àti ní òru pẹ̀lú agbárakáká, làálàá ati aápọn, kí àwá má baà jẹ́ àjàgà fún yín. \v 9 Àwa ṣìṣe èyí láti jẹ́ àpẹre rere fún yín àti pé, ki ẹ̀yin le tẹ̀lé àwòkọ́ṣe wa, kìí ṣepé àwa kòní àṣẹ.

1
03/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Nígbàtí a wà pẹ̀lú yín, a paá láṣe fún yín pé, tí ẹnikẹ́ni kò bá fé ṣiṣẹ́ kò gbọdọ̀ jẹun. \v 11 Nítorí a gbọ́ pé àwọn kan ńṣe ìmẹ́lẹ́ làárín yín, wọn kò ṣiṣẹ́ ṣùgbón dípò wọn ń fínràn. \v 12 Nísinsiǹyí, irúfẹ́ àwọn ènìyán yí ni a paá láṣẹ tí asìgbà níyáǹjú nínú Olúwa pé, kí wọ́n máa ṣisẹ ní ìdákẹ́rọ́rọ́ àti pé kí wọ́n máa je nínú oúnje ara won.

1
03/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 Ẹ má ṣe jẹ́kí ọkàn yín fà kúrò nínú ṣíse ohun tí ó tọ́. \v 14 Bí ẹnikéni kò bá gba ọ̀rọ̀ tí a kọ sínú ìwé yìí gbọ́, ẹ kíyèsí rẹ̀, kí ẹ má sìṣe ní ohun kankan ṣe pèlú rẹ̀, kí ojú leè tìí. \v 15 Máṣe ríì gẹ́gẹ́ bi ọ̀tá, ṣùgbọ́n kì í nílọ̀ bí arákùnrin rẹ.

1
03/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Ǹjẹ́ kí Ọlọ́run àláfíà fún yín ní àláfíà ní gbogbo ọ̀nà àti ní gbogbo ìgbà. Kí Ọlọ́run wà pẹ̀lú yín. \v 17 Èyí ni ìkini, láti ọwọ́ pọ́ọ̀lù wá, tíí se àmì nínú àwọn ìwé tí mo kọ. Èyí ni bí Moṣe ń kọ̀wé. \v 18 Ǹjẹ́, kí ore ọ̀fẹ́ Olúwa wa Jésù krístì wà pèlú yín. Àmín

1
03/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹta

29
LICENSE.md Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
# License
## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0)
This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/.
### You are free to:
* **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format
* **Adapt** — remix, transform, and build upon the material
for any purpose, even commercially.
The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms.
### Under the following conditions:
* **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work.
* **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original.
**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits.
### Notices:
You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation.
No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material.
This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/).

60
manifest.json Normal file
View File

@ -0,0 +1,60 @@
{
"package_version": 7,
"format": "usfm",
"generator": {
"name": "ts-desktop",
"build": "5"
},
"target_language": {
"id": "yo",
"name": "Yorùbá",
"direction": "ltr"
},
"project": {
"id": "2th",
"name": "2 Thessalonians"
},
"type": {
"id": "text",
"name": "Text"
},
"resource": {
"id": "reg",
"name": "Regular"
},
"source_translations": [
{
"language_id": "en",
"resource_id": "ulb",
"checking_level": "3",
"date_modified": "2017-11-29T00:00:00+00:00",
"version": "12"
}
],
"parent_draft": {},
"translators": [
"Adio F. Oluwatobiloba "
],
"finished_chunks": [
"01-title",
"01-01",
"01-03",
"01-06",
"01-09",
"01-11",
"02-01",
"02-03",
"02-05",
"02-08",
"02-11",
"02-13",
"02-16",
"03-title",
"03-01",
"03-04",
"03-06",
"03-10",
"03-13",
"03-16"
]
}