adesinaabegunde_yo_2th_text.../02/05.txt

1 line
381 B
Plaintext

\v 5 Ẹ̀yin kò rántí pé nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín mo sọ nǹkan wọ̀nyìí? \v 6 Nísinsìnyí ẹ̀yín mọ ohun tí ó ń se ìdènà, pé kí á le fihàn ní àkókò tí ó tọ́ nìkan. \v 7 Nítorí ohun ìjìnlẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́, kìki pé ẹnìkan wà tí ó ń se ìdènà fun nísinsìnyí títí a ó fi mu kúrò lọ́nà.