adesinaabegunde_yo_2th_text.../03/10.txt

1 line
503 B
Plaintext

\v 10 Nígbàtí a wà pẹ̀lú yín, a paá láṣe fún yín pé, tí ẹnikẹ́ni kò bá fé ṣiṣẹ́ kò gbọdọ̀ jẹun. \v 11 Nítorí a gbọ́ pé àwọn kan ńṣe ìmẹ́lẹ́ làárín yín, wọn kò ṣiṣẹ́ ṣùgbón dípò wọn ń fínràn. \v 12 Nísinsiǹyí, irúfẹ́ àwọn ènìyán yí ni a paá láṣẹ tí asìgbà níyáǹjú nínú Olúwa pé, kí wọ́n máa ṣisẹ ní ìdákẹ́rọ́rọ́ àti pé kí wọ́n máa je nínú oúnje ara won.