adesinaabegunde_yo_2th_text.../01/11.txt

1 line
467 B
Plaintext

\v 11 Nítorí eyi à ń gbàdúrà nígbàgbogbo fun yín. À gbàdúrà pé Ọlọ́run wa yóò kà yín yẹ fún ìpè yín. Àti pé kí ó le mú gbogbo èrò rere àti gbogbo iṣẹ́ ìgbàgbọ́ ṣẹ pẹ̀lú agbára. \v 12 A gbàdúrà nǹkan wọ̀nyìí kí orúkọ Jésù Olúwa wa le è di gbígbéga nípa yín. A gbàdúrà pé kí ẹ di ẹni íse lógo nípa Rẹ̀, nítorí ore-ọ́fẹ́ Ọlọ́run wa àti Olúwa wa Jésu Kristì.