adesinaabegunde_yo_2th_text.../01/06.txt

1 line
443 B
Plaintext

\v 6 Òdodo ni fún Ọlọ́run láti dá ìpọ́njú padà sì ọ̀dọ̀ àwọn tí ó ń pọ̀n yín lójú, \v 7 Àti ìtura fún ẹ̀yin tí a pọ́n lójú pẹ̀lú wa. Yóò se èyí nígbà ìfarahàn Jésù Olúwa láti Ọrun wá pẹ̀lú àwọn ángẹ́lì alágbára Rẹ̀. \v 8 Nínú ọ̀wọ́ iná ni yóò gba ẹ̀san lára àwọn tí kò mọ Ọlọ́run àti àwọn tí kò gba ìhìnrere Jésù Olúwa wa.