Thu May 20 2021 15:12:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
f34b824242
commit
52be9f7771
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, ‘Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.”
|
||||
\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, ‘Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara à rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju èyí lọ.”
|
|
@ -0,0 +1,4 @@
|
|||
\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. Àti kí a fi gbogbo àyà, àti gbogbo òye, àti gbogbo ọkàn àti gbogbo agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.”
|
||||
34Jesu rí i dájú pé òye ọkùnrin yìí ga, nítorí náà, Jesu sọ fún un pé, “Arákùnrin, ìwọ kò jìnà sí à ti dé ìjọba Ọ̀run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu.
|
||||
Ọmọ ta ni Kristi ń ṣe?
|
||||
\v 33 \v 34 dd
|
|
@ -101,6 +101,7 @@
|
|||
"12-18",
|
||||
"12-20",
|
||||
"12-24",
|
||||
"12-26"
|
||||
"12-26",
|
||||
"12-28"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue