Thu May 20 2021 15:10:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 15:10:13 +01:00
parent caee1025be
commit f34b824242
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn òfin ni èyí tí ó kà báyìí pé: Gbọ́ Israẹli; Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, èyí ní òfin kìn-ín-ní. \v 31 Èkejì ni pé: Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ. Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.”
\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara rẹ. Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.”