From f34b8242426c2d69ae984379764fa6f313716987 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 15:10:13 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 15:10:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 12/28.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/12/28.txt b/12/28.txt index 4e42cf6..b599676 100644 --- a/12/28.txt +++ b/12/28.txt @@ -1 +1 @@ -\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn òfin ni èyí tí ó kà báyìí pé: ‘Gbọ́ Israẹli; Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, èyí ní òfin kìn-ín-ní.’ \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.” \ No newline at end of file +\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, ‘Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.” \ No newline at end of file