From 52be9f77718bbad5393accd2412e4fcb9aa653f9 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 15:12:13 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 15:12:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 12/28.txt | 2 +- 12/32.txt | 4 ++++ manifest.json | 3 ++- 3 files changed, 7 insertions(+), 2 deletions(-) create mode 100644 12/32.txt diff --git a/12/28.txt b/12/28.txt index b599676..fc2b816 100644 --- a/12/28.txt +++ b/12/28.txt @@ -1 +1 @@ -\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, ‘Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.” \ No newline at end of file +\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, ‘Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara à rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju èyí lọ.” \ No newline at end of file diff --git a/12/32.txt b/12/32.txt new file mode 100644 index 0000000..b210499 --- /dev/null +++ b/12/32.txt @@ -0,0 +1,4 @@ +\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. Àti kí a fi gbogbo àyà, àti gbogbo òye, àti gbogbo ọkàn àti gbogbo agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” +34Jesu rí i dájú pé òye ọkùnrin yìí ga, nítorí náà, Jesu sọ fún un pé, “Arákùnrin, ìwọ kò jìnà sí à ti dé ìjọba Ọ̀run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu. +Ọmọ ta ni Kristi ń ṣe? +\v 33 \v 34 dd \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 0896172..b3cf070 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -101,6 +101,7 @@ "12-18", "12-20", "12-24", - "12-26" + "12-26", + "12-28" ] } \ No newline at end of file