Tue Oct 22 2019 21:10:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-22 21:10:36 +01:00
parent d801a8ec9c
commit 9edff306b3
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Kìí ṣe pé mo ti gba àwọn nǹkan wọ̀nyí, tàbí pé mo ti di pípé. Ṣùgbọ́n èmi ńlàkàkà kí èmi kí ó le ṣe àrígbámú ohun tí Krístì Jésù torí rẹ̀ gbámimú. \v 13 Ẹ̀yin ará, èmi kò rò pé èmi tìkara mi ti ṣe àrígbámú rẹ̀. Ṣùgbọ́n ohun kan ni o: mò ń gbàgbé ohun tí ó ti bọ́ sẹ́yìn mo sì ń nàgà wo ohun tó wà lọ́ọ̀ọ́kán. \v 14 Mò ń lépa àfojúsùn náà láti le gba e
\v 12 Kìí ṣe pé mo ti gba àwọn nǹkan wọ̀nyí, tàbí pé mo ti di pípé. Ṣùgbọ́n èmi ńlàkàkà kí èmi kí ó le ṣe àrígbámú ohun tí Krístì Jésù torí rẹ̀ gbámimú. \v 13 Ẹ̀yin ará, èmi kò rò pé èmi tìkara mi ti ṣe àrígbámú rẹ̀. Ṣùgbọ́n ohun kan ni o: mò ń gbàgbé ohun tí ó ti bọ́ sẹ́yìn mo sì ń nàgà wo ohun tó wà lọ́ọ̀ọ́kán. \v 14 Mò ń lépa àfojúsùn náà láti le gba èrè ìpè gíga ti Ọlọ́run nínú Krísti Jésu.