From 9edff306b3398bdd30e8a1c13c79560ac8d3a984 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Tue, 22 Oct 2019 21:10:36 +0100 Subject: [PATCH] Tue Oct 22 2019 21:10:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 03/12.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/03/12.txt b/03/12.txt index 62c8018..e2357c9 100644 --- a/03/12.txt +++ b/03/12.txt @@ -1 +1 @@ -\v 12 Kìí ṣe pé mo ti gba àwọn nǹkan wọ̀nyí, tàbí pé mo ti di pípé. Ṣùgbọ́n èmi ńlàkàkà kí èmi kí ó le ṣe àrígbámú ohun tí Krístì Jésù torí rẹ̀ gbámimú. \v 13 Ẹ̀yin ará, èmi kò rò pé èmi tìkara mi ti ṣe àrígbámú rẹ̀. Ṣùgbọ́n ohun kan ni o: mò ń gbàgbé ohun tí ó ti bọ́ sẹ́yìn mo sì ń nàgà wo ohun tó wà lọ́ọ̀ọ́kán. \v 14 Mò ń lépa àfojúsùn náà láti le gba e \ No newline at end of file +\v 12 Kìí ṣe pé mo ti gba àwọn nǹkan wọ̀nyí, tàbí pé mo ti di pípé. Ṣùgbọ́n èmi ńlàkàkà kí èmi kí ó le ṣe àrígbámú ohun tí Krístì Jésù torí rẹ̀ gbámimú. \v 13 Ẹ̀yin ará, èmi kò rò pé èmi tìkara mi ti ṣe àrígbámú rẹ̀. Ṣùgbọ́n ohun kan ni o: mò ń gbàgbé ohun tí ó ti bọ́ sẹ́yìn mo sì ń nàgà wo ohun tó wà lọ́ọ̀ọ́kán. \v 14 Mò ń lépa àfojúsùn náà láti le gba èrè ìpè gíga ti Ọlọ́run nínú Krísti Jésu. \ No newline at end of file