Thu Jan 02 2020 15:18:01 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2020-01-02 15:18:02 +01:00
parent 14023a719b
commit b6a306947a
2 changed files with 1 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Fún ìdí èyí Ọlọ́run pàápàá wá gbé E ga gidi gan. Ó fún Un lórúkọ tó borí gbogbo orúkọ. \v 10 Ó ṣe èyí kí ó le jẹ́ pé ní orúkọ Jésù gbogbo erúnkún yóò máa ba búúbúú, àwọn tó wà lọ́run àti àwọn tó wà lórí ilẹ̀ àti àwọn tó wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀. \v 11 Ó ṣe èyí kí gbogbo ahọ́n le jẹ́wọ́ pé Jésù Krístì ni Olúwa, fún ògo Ọlọ́run Baba.
\v 9 Fún ìdí èyí Ọlọ́run pàápàá wá gbé E ga gidi gan. Ó fún Un lórúkọ tó borí gbogbo orúkọ. \v 10 Ó ṣe èyí kí ó le jẹ́ pé ní orúkọ Jésù gbogbo erúnkún yóò máa wólẹ̀, àwọn tó wà lọ́run àti àwọn tó wà lórí ilẹ̀ àti àwọn tó wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀. \v 11 Ó ṣe èyí kí gbogbo ahọ́n le jẹ́wọ́ pé Jésù Krístì ni Olúwa, fún ògo Ọlọ́run Baba.

View File

@ -53,7 +53,6 @@
"02-01",
"02-03",
"02-05",
"02-09",
"02-12",
"02-14",
"02-17",