Thu Jan 02 2020 15:12:02 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2020-01-02 15:12:03 +01:00
parent 978e21e0d9
commit 14023a719b
2 changed files with 3 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 28 Ẹ máṣe jẹ́ kí àwọn alátakò yín kí ó da jìnnìjìnnì bò yín bí tií wulẹ̀ kó mọ. Èyí jẹ́ àmì fún wọn fún ìparun wọn, ṣùgbọ́n fún ìgbàlà yín - láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run sì ni èyí. \v 29 Nítorí a ti fi fún un yín, nítorí Krístì, kì í ṣe láti gbà á gbọ́ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí Rẹ̀ pẹ̀lú, \v 30 kí ẹ̀yín kí o ní ìpòrúru kan náà tí ẹ rí tí mo ní, tí ẹ sì gbọ́ tí mo ń sọ nísinsìnyí.
\v 28 Ẹ máṣe jẹ́ kí àwọn alátakò yín kí ó da jìnnìjìnnì bò yín bí tií wulẹ̀ kó mọ. Èyí jẹ́ àmì fún wọn fún ìparun wọn, ṣùgbọ́n fún ìgbàlà yín - láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run sì ni èyí. \v 29 Nítorí a ti fi fún un yín, nítorí Krístì, kì í ṣe láti gbà á gbọ́ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí Rẹ̀ pẹ̀lú, \v 30 kí ẹ̀yín kí ó ní ìlàkọjá kan náà tí ẹ rí tí mo ní, tí ẹ sì gbọ́ tí mo ń sọ nísinsìnyí.

View File

@ -48,6 +48,8 @@
"01-20",
"01-22",
"01-25",
"01-28",
"02-title",
"02-01",
"02-03",
"02-05",