Wed Jul 03 2019 07:13:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-03 07:13:21 +01:00
parent 06af95b08b
commit 7b5af3401b
3 changed files with 3 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Ǹjẹ́, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìyìnrere gbilẹ̀ síi. \v 13 Nítorí ìdí èyí, ó ti di mímọ̀ fún gbogbo àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin àti àwọn yókù pé mo jẹ́ òǹdè fún Krístì. \v 14 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ni wọ́n ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run síi nítorí ìdè mi tí wọ́n sì ní ìgboyà láti sọ ọ̀rọ̀ náà.
\v 12 Ǹjẹ́, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìhìnrere gbilẹ̀ síi. \v 13 Nítorí ìdí èyí, ó ti di mímọ̀ fún gbogbo àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin àti àwọn yókù pé mo jẹ́ òǹdè fún Krístì. \v 14 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ni wọ́n ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run síi nítorí ìdè mi tí wọ́n sì ní ìgboyà láti sọ ọ̀rọ̀ náà.

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú ọkàn kan. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìyìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè.
\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú ọkàn kan. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìhìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn yóò pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè.

1
01/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 \v 19 n