From 7b5af3401b2ea56101bd7e57ee943a61883159d3 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Wed, 3 Jul 2019 07:13:21 +0100 Subject: [PATCH] Wed Jul 03 2019 07:13:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 01/12.txt | 2 +- 01/15.txt | 2 +- 01/18.txt | 1 + 3 files changed, 3 insertions(+), 2 deletions(-) create mode 100644 01/18.txt diff --git a/01/12.txt b/01/12.txt index fa18dc9..ef0583f 100644 --- a/01/12.txt +++ b/01/12.txt @@ -1 +1 @@ -\v 12 Ǹjẹ́, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìyìnrere gbilẹ̀ síi. \v 13 Nítorí ìdí èyí, ó ti di mímọ̀ fún gbogbo àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin àti àwọn yókù pé mo jẹ́ òǹdè fún Krístì. \v 14 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ni wọ́n ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run síi nítorí ìdè mi tí wọ́n sì ní ìgboyà láti sọ ọ̀rọ̀ náà. \ No newline at end of file +\v 12 Ǹjẹ́, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi ti mú kí ìhìnrere gbilẹ̀ síi. \v 13 Nítorí ìdí èyí, ó ti di mímọ̀ fún gbogbo àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin àti àwọn yókù pé mo jẹ́ òǹdè fún Krístì. \v 14 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ni wọ́n ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run síi nítorí ìdè mi tí wọ́n sì ní ìgboyà láti sọ ọ̀rọ̀ náà. \ No newline at end of file diff --git a/01/15.txt b/01/15.txt index b4e6071..e11f9a3 100644 --- a/01/15.txt +++ b/01/15.txt @@ -1 +1 @@ -\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú ọkàn kan. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìyìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn lè pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè. \ No newline at end of file +\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú ọkàn kan. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìhìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn yóò pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè. \ No newline at end of file diff --git a/01/18.txt b/01/18.txt new file mode 100644 index 0000000..58cd8dc --- /dev/null +++ b/01/18.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 18 \v 19 n \ No newline at end of file