Tue May 18 2021 21:14:42 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 21:14:43 +01:00
parent 561caccc75
commit f7e41b0816
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 26 Ó sì tún sọ pé, “Ìjọba Ọlọ́run dàbí okùnrin kan tí ó ń fúnrúgbìn sí ilẹ̀. \v 27 Ó ń sùn ní óru àti ní ọ̀sán ó dìde, irúgbìn náà hu jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀. \v 28 Nítorí tí ilẹ̀ hù èso jáde fún ara rẹ̀: ó mú èéhù ewé jáde, lẹ́yìn náà ní orí ọkà, ní ìparí ní orí ọkà tí ó ti gbó. \v 29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, ó sì kórè rẹ̀.”
Òwe musitadi
\v 26 Ó sì tún sọ pé, “Ìjọba Ọlọ́run dàbí okùnrin kan tí ó ń fúnrúgbìn sí ilẹ̀. \v 27 Ó ń sùn ní óru àti ní ọ̀sán ó dìde, irúgbìn náà hu jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀. \v 28 Nítorí tí ilẹ̀ hù èso jáde fún ara rẹ̀: ó mú èéhù ewé jáde, lẹ́yìn náà ní orí ọkà, ní ìparí ní orí ọkà tí ó ti gbó. \v 29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, nítorí ìkórè ti dé."

1
04/30.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, Òwe wo ni kí èmi fi ṣe àkàwé rẹ̀? 31Ó dàbí èso hóró musitadi kan, lóòótọ́, ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. 32Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ. Ó sì yọ ẹ̀ka ńlá níbi tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí, kí wọn sì rí ìdáàbòbò.”\v 31 \v 32 ss

View File

@ -66,6 +66,7 @@
"04-16",
"04-18",
"04-21",
"04-24"
"04-24",
"04-26"
]
}