From f7e41b0816a2a9a5c6cfe3ab1fd7d8415926dd19 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Tue, 18 May 2021 21:14:43 +0100 Subject: [PATCH] Tue May 18 2021 21:14:42 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 04/26.txt | 3 +-- 04/30.txt | 1 + manifest.json | 3 ++- 3 files changed, 4 insertions(+), 3 deletions(-) create mode 100644 04/30.txt diff --git a/04/26.txt b/04/26.txt index 66dfa14..24af0ea 100644 --- a/04/26.txt +++ b/04/26.txt @@ -1,2 +1 @@ -\v 26 Ó sì tún sọ pé, “Ìjọba Ọlọ́run dàbí okùnrin kan tí ó ń fúnrúgbìn sí ilẹ̀. \v 27 Ó ń sùn ní óru àti ní ọ̀sán ó dìde, irúgbìn náà hu jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀. \v 28 Nítorí tí ilẹ̀ hù èso jáde fún ara rẹ̀: ó mú èéhù ewé jáde, lẹ́yìn náà ní orí ọkà, ní ìparí ní orí ọkà tí ó ti gbó. \v 29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, ó sì kórè rẹ̀.” -Òwe musitadi \ No newline at end of file +\v 26 Ó sì tún sọ pé, “Ìjọba Ọlọ́run dàbí okùnrin kan tí ó ń fúnrúgbìn sí ilẹ̀. \v 27 Ó ń sùn ní óru àti ní ọ̀sán ó dìde, irúgbìn náà hu jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀. \v 28 Nítorí tí ilẹ̀ hù èso jáde fún ara rẹ̀: ó mú èéhù ewé jáde, lẹ́yìn náà ní orí ọkà, ní ìparí ní orí ọkà tí ó ti gbó. \v 29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, nítorí ìkórè ti dé." \ No newline at end of file diff --git a/04/30.txt b/04/30.txt new file mode 100644 index 0000000..0d79d93 --- /dev/null +++ b/04/30.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, Òwe wo ni kí èmi fi ṣe àkàwé rẹ̀? 31Ó dàbí èso hóró musitadi kan, lóòótọ́, ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. 32Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ. Ó sì yọ ẹ̀ka ńlá níbi tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí, kí wọn sì rí ìdáàbòbò.”\v 31 \v 32 ss \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 93bc601..2a6dd0c 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -66,6 +66,7 @@ "04-16", "04-18", "04-21", - "04-24" + "04-24", + "04-26" ] } \ No newline at end of file