Wed Jun 26 2019 10:01:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 10:01:27 +01:00
parent b3aa88e52d
commit e5de4a3f98
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn.
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn.