diff --git a/15/06.txt b/15/06.txt index 1e4790a..f81d9d2 100644 --- a/15/06.txt +++ b/15/06.txt @@ -1 +1 @@ -\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file +\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file