Wed Jun 26 2019 10:07:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 10:07:27 +01:00
parent c05f65750d
commit 89b4fbf0c8
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí bi léèrè pé kí ó se oun tí óó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn.
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí bi léèrè pé kí ó se oun tí ó tí n se tẹ́lẹ̀ fún wọn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Sé ẹfẹ̀ kí èmi fi Ọba àwọn Júù sílẹ̀ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfa fi lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀.
\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ̀ kí èmi fi Ọba àwọn Júù sílẹ̀ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfa fi lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀.

View File

@ -38,7 +38,7 @@
"finished_chunks": [
"15-01",
"15-04",
"15-09",
"15-06",
"15-12",
"15-14",
"15-16",