From 89b4fbf0c8c78d7005144edd7ab46a53f9ab2bc9 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Wed, 26 Jun 2019 10:07:27 +0100 Subject: [PATCH] Wed Jun 26 2019 10:07:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 15/06.txt | 2 +- 15/09.txt | 2 +- manifest.json | 2 +- 3 files changed, 3 insertions(+), 3 deletions(-) diff --git a/15/06.txt b/15/06.txt index 1c3cbe0..8492a1f 100644 --- a/15/06.txt +++ b/15/06.txt @@ -1 +1 @@ -\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí bi léèrè pé kí ó se oun tí óó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file +\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí bi léèrè pé kí ó se oun tí ó tí n se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file diff --git a/15/09.txt b/15/09.txt index 2f26237..87e33e3 100644 --- a/15/09.txt +++ b/15/09.txt @@ -1 +1 @@ -\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Sé ẹfẹ̀ kí èmi fi Ọba àwọn Júù sílẹ̀ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfa fi lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀. \ No newline at end of file +\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ̀ kí èmi fi Ọba àwọn Júù sílẹ̀ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfa fi lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 4c06e34..e01d4f9 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -38,7 +38,7 @@ "finished_chunks": [ "15-01", "15-04", - "15-09", + "15-06", "15-12", "15-14", "15-16",