Fri Jul 09 2021 09:58:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-07-09 09:58:41 +01:00
parent bde7e9ffee
commit 5c6f76dc73
5 changed files with 4 additions and 5 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹ̀ta yó dìde
\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹ̀ta yó dìde.

View File

@ -1 +1 @@
\v 35 Jákọ́bù àti Jòhánnù, àwọn ọmọ Ṣébédè gòkè wá sọ́dọ́ rẹ̀ wọ́n wípé, "Olùkọni, àwa fẹ́ kí ẹ se ohunkóhun tí a bá bèrè fún wa" \v 36 Ó bi wọ́n pé, kínni ẹ fẹ́ kí èmi ó se fún yín?" \v 37 " Wọ́n wípé, gbà wá láàyè láti jókòó pẹ̀lú rẹ nínú ògo, ọ̀kan lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ àti èkejì ní ọwọ́ òsì rẹ."
\v 35 Jákọ́bù àti Jòhánnù, àwọn ọmọ Ṣébédè gòkè wá sọ́dọ́ rẹ̀ wọ́n wípé, "Olùkọni, àwa fẹ́ kí ẹ se ohunkóhun tí a bá bèrè fún wa" \v 36 Ó bi wọ́n pé, kínni ẹ fẹ́ kí èmi ó se fún yín?" \v 37 "Wọ́n wípé, gbà wá láàyè láti jókòó pẹ̀lú rẹ nínú ògo, ọ̀kan lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ àti èkejì ní ọwọ́ òsì rẹ."

View File

@ -1 +1 @@
\v 41 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́ẹ̀wá yó kù gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí Jákọ́bù àti Jòhánnù. \v 42 Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ó wípé, "ẹ̀yín mọ̀ pé àwọn tí a kà sí olórí láàrín àwọn kèfèrí má ńlo ipá lórí wọn àti àwọn alásẹ àgbà ńlo ipò àsẹ lórí wọn
\v 41 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́ẹ̀wá yó kù gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí Jákọ́bù àti Jòhánnù. \v 42 Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ó wípé, "ẹ̀yín mọ̀ pé àwọn tí a kà sí olórí láàrín àwọn kèfèrí má ńlo ipá lórí wọn àti àwọn alásẹ àgbà ńlo ipò àsẹ lórí wọn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 43 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà ọ̀pọ̀lọpọ̀"
\v 43 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà ọ̀pọ̀lọpọ̀."

View File

@ -231,7 +231,6 @@
"10-38",
"10-41",
"10-43",
"10-46",
"10-49",
"10-51",
"11-01",