diff --git a/10/32.txt b/10/32.txt index dc1b83f..bfde7af 100644 --- a/10/32.txt +++ b/10/32.txt @@ -1 +1 @@ -\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹ̀ta yó dìde \ No newline at end of file +\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹ̀ta yó dìde. \ No newline at end of file diff --git a/10/35.txt b/10/35.txt index f8be884..3b9cd64 100644 --- a/10/35.txt +++ b/10/35.txt @@ -1 +1 @@ -\v 35 Jákọ́bù àti Jòhánnù, àwọn ọmọ Ṣébédè gòkè wá sọ́dọ́ rẹ̀ wọ́n wípé, "Olùkọni, àwa fẹ́ kí ẹ se ohunkóhun tí a bá bèrè fún wa" \v 36 Ó bi wọ́n pé, kínni ẹ fẹ́ kí èmi ó se fún yín?" \v 37 " Wọ́n wípé, gbà wá láàyè láti jókòó pẹ̀lú rẹ nínú ògo, ọ̀kan lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ àti èkejì ní ọwọ́ òsì rẹ." \ No newline at end of file +\v 35 Jákọ́bù àti Jòhánnù, àwọn ọmọ Ṣébédè gòkè wá sọ́dọ́ rẹ̀ wọ́n wípé, "Olùkọni, àwa fẹ́ kí ẹ se ohunkóhun tí a bá bèrè fún wa" \v 36 Ó bi wọ́n pé, kínni ẹ fẹ́ kí èmi ó se fún yín?" \v 37 "Wọ́n wípé, gbà wá láàyè láti jókòó pẹ̀lú rẹ nínú ògo, ọ̀kan lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ àti èkejì ní ọwọ́ òsì rẹ." \ No newline at end of file diff --git a/10/41.txt b/10/41.txt index 07f038d..a9c2c0b 100644 --- a/10/41.txt +++ b/10/41.txt @@ -1 +1 @@ -\v 41 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́ẹ̀wá yó kù gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí Jákọ́bù àti Jòhánnù. \v 42 Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ó wípé, "ẹ̀yín mọ̀ pé àwọn tí a kà sí olórí láàrín àwọn kèfèrí má ńlo ipá lórí wọn àti àwọn alásẹ àgbà ńlo ipò àsẹ lórí wọn \ No newline at end of file +\v 41 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́ẹ̀wá yó kù gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí Jákọ́bù àti Jòhánnù. \v 42 Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ó wípé, "ẹ̀yín mọ̀ pé àwọn tí a kà sí olórí láàrín àwọn kèfèrí má ńlo ipá lórí wọn àti àwọn alásẹ àgbà ńlo ipò àsẹ lórí wọn. \ No newline at end of file diff --git a/10/43.txt b/10/43.txt index 5766274..b51cdfb 100644 --- a/10/43.txt +++ b/10/43.txt @@ -1 +1 @@ -\v 43 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà ọ̀pọ̀lọpọ̀" \ No newline at end of file +\v 43 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà ọ̀pọ̀lọpọ̀." \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 3659cad..a644743 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -231,7 +231,6 @@ "10-38", "10-41", "10-43", - "10-46", "10-49", "10-51", "11-01",