Wed May 26 2021 11:43:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 11:43:44 +01:00
parent 6bd9127aa9
commit 3748af1e5e
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti nderu arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e.
\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Áńdérù arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi awọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e.

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sinagọgu ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì ya wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin.
\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sínágọ́g ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì ya wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin.

View File

@ -44,8 +44,8 @@
"01-09",
"01-12",
"01-14",
"01-16",
"01-19",
"01-21",
"01-23",
"01-27",
"01-29",