diff --git a/01/16.txt b/01/16.txt index b15ef8d..b1f2e9a 100644 --- a/01/16.txt +++ b/01/16.txt @@ -1 +1 @@ -\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti nderu arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e. \ No newline at end of file +\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Áńdérù arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi awọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e. \ No newline at end of file diff --git a/01/21.txt b/01/21.txt index 392bea4..ebf145e 100644 --- a/01/21.txt +++ b/01/21.txt @@ -1 +1 @@ -\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sinagọgu ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì ya wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin. \ No newline at end of file +\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sínágọ́g ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì ya wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index eaa6b1c..f042a86 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -44,8 +44,8 @@ "01-09", "01-12", "01-14", + "01-16", "01-19", - "01-21", "01-23", "01-27", "01-29",