Wed May 26 2021 12:17:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
03026f1c0c
commit
16d008c36d
|
@ -1 +1 @@
|
||||||
\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Betisaida. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?”
|
\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Bẹtisaídà. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?”
|
|
@ -1 +1 @@
|
||||||
\v 24 Ó wo okè, ó wípé, “Mo rí àwọn ènìyàn ti wọ́n n rìn kiri bí igi.” \v 25 Nígbà náà, Jesu tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ̀, ọkùnrin náà sì la ojú u rẹ̀, a dá ìran rẹ̀ padà, ó sì rí gbogbo nǹkan kedere. \v 26 Jesu sì rán an sí ilé e rẹ̀, Ó wí fún n pé, “Má ṣe lọ sí ìlú. "
|
\v 24 Ó wo okè, ó wípé, “Mo rí àwọn ènìyàn ti wọ́n n rìn kiri bí igi.” \v 25 Nígbànáà, Jesu tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ̀, ọkùnrin náà sì la ojú u rẹ̀, a dá ìran rẹ̀ padà, ó sì rí gbogbo nǹkan kedere. \v 26 Jesu sì rán an sí ilé e rẹ̀, Ó wí fún n pé, “Má ṣe lọ sí ìlú. "
|
|
@ -1,2 +1,2 @@
|
||||||
\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “ Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?”
|
\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?”
|
||||||
Peteru dáhùn pé, “Ìwọ ni Kristi náà.” \v 30 Jesu kìlọ̀ fún wọn, kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni nípa òun.
|
Peteru dáhùn pé, “Ìwọ ni Kristi náà.” \v 30 Jesu kìlọ̀ fún wọn, kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni nípa òun.
|
Loading…
Reference in New Issue