diff --git a/08/22.txt b/08/22.txt index 4e5eb0f..6a34e74 100644 --- a/08/22.txt +++ b/08/22.txt @@ -1 +1 @@ -\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Betisaida. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?” \ No newline at end of file +\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Bẹtisaídà. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?” \ No newline at end of file diff --git a/08/24.txt b/08/24.txt index 41fcf11..18aecec 100644 --- a/08/24.txt +++ b/08/24.txt @@ -1 +1 @@ -\v 24 Ó wo okè, ó wípé, “Mo rí àwọn ènìyàn ti wọ́n n rìn kiri bí igi.” \v 25 Nígbà náà, Jesu tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ̀, ọkùnrin náà sì la ojú u rẹ̀, a dá ìran rẹ̀ padà, ó sì rí gbogbo nǹkan kedere. \v 26 Jesu sì rán an sí ilé e rẹ̀, Ó wí fún n pé, “Má ṣe lọ sí ìlú. " \ No newline at end of file +\v 24 Ó wo okè, ó wípé, “Mo rí àwọn ènìyàn ti wọ́n n rìn kiri bí igi.” \v 25 Nígbànáà, Jesu tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ̀, ọkùnrin náà sì la ojú u rẹ̀, a dá ìran rẹ̀ padà, ó sì rí gbogbo nǹkan kedere. \v 26 Jesu sì rán an sí ilé e rẹ̀, Ó wí fún n pé, “Má ṣe lọ sí ìlú. " \ No newline at end of file diff --git a/08/29.txt b/08/29.txt index 0c743f4..3687961 100644 --- a/08/29.txt +++ b/08/29.txt @@ -1,2 +1,2 @@ -\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “ Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?” +\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?” Peteru dáhùn pé, “Ìwọ ni Kristi náà.” \v 30 Jesu kìlọ̀ fún wọn, kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni nípa òun. \ No newline at end of file