Wed May 26 2021 12:17:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 12:17:44 +01:00
parent 03026f1c0c
commit 16d008c36d
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Betisaida. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?” \v 22 Nígbà tí wọ́n dé Bẹtisaídà. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?”