Thu May 20 2021 15:24:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 15:24:13 +01:00
parent 8dca5b4c8f
commit 1676cadb7c
1 changed files with 1 additions and 3 deletions

View File

@ -1,6 +1,4 @@
\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì?
\v 36 Dafidi tìkára rẹ̀, ti ń ti ipa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé:
Olúwa sọ fún Olúwa mi pé:
\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì? \v 36 Dafidi tìkára rẹ̀, nípa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé, “Olúwa sọ fún Olúwa mi pé:
“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi,
títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ
di àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.” ’\v 37 Níwọ́n ìgbà tí Dafidi tìkára rẹ̀ pè é ní Olúwa, Báwo ni ó túnṣe lè jẹ́ ọmọ rẹ̀?”