diff --git a/12/35.txt b/12/35.txt index 888000e..d0631a9 100644 --- a/12/35.txt +++ b/12/35.txt @@ -1,6 +1,4 @@ -\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì? -\v 36 Dafidi tìkára rẹ̀, ti ń ti ipa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé: -“ ‘Olúwa sọ fún Olúwa mi pé: +\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì? \v 36 Dafidi tìkára rẹ̀, nípa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé, “ ‘Olúwa sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.” ’\v 37 Níwọ́n ìgbà tí Dafidi tìkára rẹ̀ pè é ní ‘Olúwa,’ Báwo ni ó túnṣe lè jẹ́ ọmọ rẹ̀?”