Wed May 26 2021 09:12:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 09:12:43 +01:00
parent 64f58b76c2
commit c41c972175
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 Arákùnrin yóò jọ̀wọ́ arákùnrin rẹ̀ fún ikú, àti bàbá ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ yóò dìde lòdì sí àwọn òbí wọn láti jẹ́ kí wọ́n pa wọ́n. \v 22 A ó kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n, ẹnití ó bá forítǐ dé òpin, ni a ó gbàlà. \v 23 Nígbàtí wọ́n bá pọ́nyínlójú ní ìlú yǐ, ẹ sá lọ sí òmíràn, nítorí looto ni mo wí fún yín, ẹ kò tí ì le la gbogbo ìlú Israeli kọjá tán kí Ọmọ Ènìyan yíò fi dé.
\v 21 Arákùnrin yóò jọ̀wọ́ arákùnrin rẹ̀ fún ikú, àti bàbá ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ yóò dìde lòdì sí àwọn òbí wọn láti jẹ́ kí wọ́n pa wọ́n. \v 22 A ó kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n, ẹnití ó bá forítǐ dé òpin, ni a ó gbàlà. \v 23 Nígbàtí wọ́n bá pọ́nyínlójú ní ìlú yǐ, ẹ sá lọ sí òmíràn, nítorí looto ni mo wí fún yín, ẹ kò tí ì le la gbogbo ìlú Israeli kọjá tán kí Ọmọ Ènìyan yóò fi dé.

View File

@ -1 +1 @@
\v 24 Ọmọ-ẹ̀yìn kò ju olùkọ́ rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ. \v 25 Ó tó fún ọmọ ẹ̀yìn kí ó dàbí olùkọ́ rẹ̀, àti fún ẹrú bí oluwa rẹ̀. Bí wọ́n bá pe baálé ilé ní Beelisebulu, orúkọ búburú wo ni wọn yóo pe àwọn ẹni tí ó ń gbé inú ilé rẹ̀!
\v 24 Ọmọ-ẹ̀yìn kò ju olùkọ́ rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹrú kò ju olúwa rẹ̀ lọ. \v 25 Ó tó fún ọmọ ẹ̀yìn kí ó dàbí olùkọ́ rẹ̀, àti fún ẹrú bí olúwa rẹ̀. Bí wọ́n bá pe baálé ilé ní Beelisebulu, orúkọ búburú wo ni wọn yóo pe àwọn ẹni tí ó ń gbé inú ilé rẹ̀!

View File

@ -46,7 +46,7 @@
"10-14",
"10-16",
"10-19",
"10-24",
"10-21",
"10-26",
"10-28",
"10-32",