From c41c972175c1d22cb784bc7ed33ffde03364b9be Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Wed, 26 May 2021 09:12:43 +0100 Subject: [PATCH] Wed May 26 2021 09:12:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 10/21.txt | 2 +- 10/24.txt | 2 +- manifest.json | 2 +- 3 files changed, 3 insertions(+), 3 deletions(-) diff --git a/10/21.txt b/10/21.txt index fb25b7e6..befc4693 100644 --- a/10/21.txt +++ b/10/21.txt @@ -1 +1 @@ -\v 21 Arákùnrin yóò jọ̀wọ́ arákùnrin rẹ̀ fún ikú, àti bàbá ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ yóò dìde lòdì sí àwọn òbí wọn láti jẹ́ kí wọ́n pa wọ́n. \v 22 A ó kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n, ẹnití ó bá forítǐ dé òpin, ni a ó gbàlà. \v 23 Nígbàtí wọ́n bá pọ́nyínlójú ní ìlú yǐ, ẹ sá lọ sí òmíràn, nítorí looto ni mo wí fún yín, ẹ kò tí ì le la gbogbo ìlú Israeli kọjá tán kí Ọmọ Ènìyan yíò fi dé. \ No newline at end of file +\v 21 Arákùnrin yóò jọ̀wọ́ arákùnrin rẹ̀ fún ikú, àti bàbá ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ yóò dìde lòdì sí àwọn òbí wọn láti jẹ́ kí wọ́n pa wọ́n. \v 22 A ó kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n, ẹnití ó bá forítǐ dé òpin, ni a ó gbàlà. \v 23 Nígbàtí wọ́n bá pọ́nyínlójú ní ìlú yǐ, ẹ sá lọ sí òmíràn, nítorí looto ni mo wí fún yín, ẹ kò tí ì le la gbogbo ìlú Israeli kọjá tán kí Ọmọ Ènìyan yóò fi dé. \ No newline at end of file diff --git a/10/24.txt b/10/24.txt index 8a8557df..cbe2ba81 100644 --- a/10/24.txt +++ b/10/24.txt @@ -1 +1 @@ -\v 24 Ọmọ-ẹ̀yìn kò ju olùkọ́ rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹrú kò ju oluwa rẹ̀ lọ. \v 25 Ó tó fún ọmọ ẹ̀yìn kí ó dàbí olùkọ́ rẹ̀, àti fún ẹrú bí oluwa rẹ̀. Bí wọ́n bá pe baálé ilé ní Beelisebulu, orúkọ búburú wo ni wọn yóo pe àwọn ẹni tí ó ń gbé inú ilé rẹ̀! \ No newline at end of file +\v 24 Ọmọ-ẹ̀yìn kò ju olùkọ́ rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹrú kò ju olúwa rẹ̀ lọ. \v 25 Ó tó fún ọmọ ẹ̀yìn kí ó dàbí olùkọ́ rẹ̀, àti fún ẹrú bí olúwa rẹ̀. Bí wọ́n bá pe baálé ilé ní Beelisebulu, orúkọ búburú wo ni wọn yóo pe àwọn ẹni tí ó ń gbé inú ilé rẹ̀! \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index bf31c9df..31d3b1ae 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -46,7 +46,7 @@ "10-14", "10-16", "10-19", - "10-24", + "10-21", "10-26", "10-28", "10-32",