Tue May 14 2019 09:25:37 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 09:25:37 +01:00
parent 33223e46fe
commit b72940196a
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Si wo o, awon kan ninu awon akowe so laarin ara won pe, "Okunrin yi nso oro odi." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nro ero ibi ninu okan yin? \v 5 Nje ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re."
\v 3 Sì wó, àwọn kan nínú àwọn akọ̀wé sọ láarín ara wọn pé, "Okùnrin yi nso oro odi." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nro ero ibi ninu okan yin? \v 5 Nje ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re."