diff --git a/09/03.txt b/09/03.txt index ce1d25c7..2765fa50 100644 --- a/09/03.txt +++ b/09/03.txt @@ -1 +1 @@ -\v 3 Si wo o, awon kan ninu awon akowe so laarin ara won pe, "Okunrin yi nso oro odi." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nro ero ibi ninu okan yin? \v 5 Nje ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re." \ No newline at end of file +\v 3 Sì wó, àwọn kan nínú àwọn akọ̀wé sọ láarín ara wọn pé, "Okùnrin yi nso oro odi." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nro ero ibi ninu okan yin? \v 5 Nje ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re." \ No newline at end of file