Fri May 17 2019 09:40:54 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 09:40:55 +01:00
parent 5978d7942a
commit 9e5fccdc43
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 51 Kíyèsi, ẹnìkan lára àwọn tí ó wà pẹ̀lú Jésù fa idà rẹ̀ yọ, ó sì gé etí ọmọ ọ̀dọ̀ olú àlùfáà kan. \v 52 Nígbànáà ni Jésù wí fun pé, "Fi idà rẹ sínú àkọ̀ rẹ̀, nítorípé gbogbo ẹni tí ó bá fi idà pa ènìyàn, ni yóò kú nípa idà" \v 53 Sé ìwọ rò pé èmi kòleè pe Bàbá, òhun yóò sì rán àwọn ángẹ́lì méjìlá tí ó jẹ́ légíóni ni? \v 54 èyí gbọdọ̀ sẹlẹ̀ kí àwọn ohun tí ati kọ sínú ìwé mímọ́ le wá sí ìmúse.
\v 51 Kíyèsi, ẹnìkan lára àwọn tí ó wà pẹ̀lú Jésù fa idà rẹ̀ yọ, ó sì gé etí ọmọ ọ̀dọ̀ olú àlùfáà kan. \v 52 Nígbà náà ni Jésù wí fun pé, "Fi idà rẹ sínú àkọ̀ rẹ̀, nítorípé gbogbo ẹni tí ó bá fi idà pa ènìyàn, ni yóò kú nípa idà" \v 53 Sé ìwọ rò pé èmi kòleè pe Bàbá, òhun yóò sì rán àwọn ángẹ́lì méjìlá tí ó jẹ́ légíóni ni? \v 54 èyí gbọdọ̀ sẹlẹ̀ kí àwọn ohun tí ati kọ sínú ìwé mímọ́ le wá sí ìmúse.