From 9e5fccdc438bf5e59042178aefb62188a4ce0eef Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Fri, 17 May 2019 09:40:55 +0100 Subject: [PATCH] Fri May 17 2019 09:40:54 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 26/51.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/26/51.txt b/26/51.txt index ee73be4a..c910364d 100644 --- a/26/51.txt +++ b/26/51.txt @@ -1 +1 @@ -\v 51 Kíyèsi, ẹnìkan lára àwọn tí ó wà pẹ̀lú Jésù fa idà rẹ̀ yọ, ó sì gé etí ọmọ ọ̀dọ̀ olú àlùfáà kan. \v 52 Nígbànáà ni Jésù wí fun pé, "Fi idà rẹ sínú àkọ̀ rẹ̀, nítorípé gbogbo ẹni tí ó bá fi idà pa ènìyàn, ni yóò kú nípa idà" \v 53 Sé ìwọ rò pé èmi kòleè pe Bàbá, òhun yóò sì rán àwọn ángẹ́lì méjìlá tí ó jẹ́ légíóni ni? \v 54 èyí gbọdọ̀ sẹlẹ̀ kí àwọn ohun tí ati kọ sínú ìwé mímọ́ le wá sí ìmúse. \ No newline at end of file +\v 51 Kíyèsi, ẹnìkan lára àwọn tí ó wà pẹ̀lú Jésù fa idà rẹ̀ yọ, ó sì gé etí ọmọ ọ̀dọ̀ olú àlùfáà kan. \v 52 Nígbà náà ni Jésù wí fun pé, "Fi idà rẹ sínú àkọ̀ rẹ̀, nítorípé gbogbo ẹni tí ó bá fi idà pa ènìyàn, ni yóò kú nípa idà" \v 53 Sé ìwọ rò pé èmi kòleè pe Bàbá, òhun yóò sì rán àwọn ángẹ́lì méjìlá tí ó jẹ́ légíóni ni? \v 54 èyí gbọdọ̀ sẹlẹ̀ kí àwọn ohun tí ati kọ sínú ìwé mímọ́ le wá sí ìmúse. \ No newline at end of file