Wed Jun 26 2019 12:06:32 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 12:06:33 +01:00
parent 4de5ea6eeb
commit 8bb5490ff3
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Bí Ó ti padà sí ìlú ní òwúrọ̀, ebi ń paá. \v 19 Ó rí igi ọ̀pọ̀tọ́ ní ẹ̀baa ojú ọ̀nà, Ó lọ sí bẹ̀, kò sì rí ohunkóhun ló rí rẹẹ̀ bíkòse ewé. Ó sọ sí igi ọ̀pọ̀tọ́ náà, ''kì yóò sí èṣo láti ara rẹ̀ mọ́,'' ní kété igi ọ̀pọ̀tọ́ náà síì gbẹ.
\v 18 Bí Ó ti padà sí ìlú ní òwúrọ̀, ebi ń paá. \v 19 Ó rí igi ọ̀pọ̀tọ́ ní ẹ̀baa ojú ọ̀nà, Ó lọ sí bẹ̀, kò sì rí ohunkóhun lórí rẹẹ̀ bíkòse ewé. Ó sọ sí igi ọ̀pọ̀tọ́ náà, ''kì yóò sí èṣo láti ara rẹ̀ mọ́,'' ní kété igi ọ̀pọ̀tọ́ náà síì gbẹ.

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yín ríi, ẹnú yà wọ́n, wọ́n sì sọ pé, ''báwo ni igi ọ̀pọ̀tọ́ náà ṣe gbẹ kíakía?'' \v 21 Jésù síì dáhùn, Ó wí fún wọn pé, ''lótìtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, tí ẹ̀yin bá ní ìgbàgbọ́ tí ẹ ò sì ṣe iyé méjì, ẹ̀yin ò ní ṣe ohun tí a ṣe sí igi ọ̀pọ̀tọ́ yìí nìkan ṣùgbọ́n ẹ̀yin ô wí fuín òkè, 'Dìde kí o sì bọ́ sínú òkun,' yóò sí rí bẹ̀. \v 22 Ohunkóhun tí ẹ̀yín bá bérè nínú àdúrà, pèlú ìgbàgbọ́, ẹ ó ríigbà.''
\v 20 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yín ríi, ẹnú yà wọ́n, wọ́n sì sọ pé, ''báwo ni igi ọ̀pọ̀tọ́ náà ṣe gbẹ kíakía?'' \v 21 Jésù síì dáhùn, Ó wí fún wọn pé, ''lótìtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, tí ẹ̀yin bá ní ìgbàgbọ́ tí ẹ kò sì ṣe iyéméjì, ẹ̀yin ò ní ṣe ohun tí a ṣe sí igi ọ̀pọ̀tọ́ yìí nìkan ṣùgbọ́n ẹ̀yin ô wí fuín òkè, 'Dìde kí o sì bọ́ sínú òkun,' yóò sí rí bẹ̀. \v 22 Ohunkóhun tí ẹ̀yín bá bérè nínú àdúrà, pèlú ìgbàgbọ́, ẹ ó ríigbà.''