Wed Jun 26 2019 12:04:32 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 12:04:33 +01:00
parent 0c217873ab
commit 4de5ea6eeb
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Lẹ́yìn náà ni Jésù wọ inú Tẹ́mpílì. Ó sì lé gbogbo àwọn tó n tà, tó n rà nínú Tẹ́mpílì, Ó da tábílì àwọn tó n ṣe pàsípárọ̀ owó pẹ̀lú ibùjókò àwọn tó n ta àdàbà. \v 13 Ó sọ fún wọn pé, ''Ati kọ́ ọ pé, 'ilé àdúrà ni a ó ma pe ilé Mìi,' ṣùgbọ́n ẹ̀yin ṣeé ní ihò àwọn adigunjalè.'' \v 14 nígbà náà ni àwọn afójú àti àwọn arọ tọ̀ọ́ wá nínú tẹ́mpílì, ó sì wò wọ́n sàn.
\v 12 Lẹ́yìn náà ni Jésù wọ inú Tẹ́mpílì. Ó sì lé gbogbo àwọn tó n tà, tó n rà nínú Tẹ́mpílì, Ó da tábílì àwọn tó n ṣe pàsípárọ̀ owó pẹ̀lú ibùjókò àwọn tó n ta àdàbà. \v 13 Ó sọ fún wọn pé, ''Ati kọ ọ́ pé, 'ilé àdúrà ni a ó ma pe ilé Mìi,' ṣùgbọ́n ẹ̀yin ṣeé ní ihò àwọn adigunjalè.'' \v 14 Nígbànáà ni àwọn afójú àti àwọn arọ tọ̀ọ́ wá nínú Tẹ́mpílì, ó sì wò wọ́n sàn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Ṣùgbọ́n nígbàtí àwọn olú àlùfáà àti àwọn akòwé rí iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe, àti ariwo àwọn ọmọ nínú tẹ́mpílì wípé, ''Hòsánà sí ọmọ Dáfídì,'' inú bí wọn gidigidi. \v 16 Wọ́n sọ fún wípé, ''Ǹ jẹ́ ìwọ gbọ́ ohun tí àwọn ènìyàn yìí ń sọ?'' Jésù síì sọ fún wọn, ''Bẹ́ẹ̀ni! ṣùgbọ́n ǹjẹ́ ẹ̀yin ò tí kà rí, 'Láti ẹnu àwọn ọmọ kékèké àti ọmọ ọwọ́ ni a ti ṣe àṣepé ìyìn'?'' \v 17 Jésù fi wọ́n sílẹ̀, ó sì lọ sí Bẹ́thánì, ó sì lo òru ọjọ́ náà ní bẹ̀.
\v 15 Ṣùgbọ́n nígbàtí àwọn olú àlùfáà àti àwọn akòwé rí iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe, àti ariwo àwọn ọmọ nínú Tẹ́mpílì wípé, ''Hòsánà sí ọmọ Dáfídì,'' inú bí wọn gidigidi. \v 16 Wọ́n sọ fún wípé, ''Ǹ jẹ́ ìwọ gbọ́ ohun tí àwọn ènìyàn yìí ń sọ?'' Jésù síì sọ fún wọn, ''Bẹ́ẹ̀ni! ṣùgbọ́n ǹjẹ́ ẹ̀yin ò tí kà rí, 'Láti ẹnu àwọn ọmọ kékèké àti ọmọ ọwọ́ ni a ti ṣe àṣepé ìyìn'?'' \v 17 Jésù fi wọ́n sílẹ̀, ó sì lọ sí Bẹ́thánì, ó sì lo òru ọjọ́ náà níbẹ̀.