adesinaabegunde_yo_mat_text.../23/06.txt

1 line
260 B
Plaintext
Raw Permalink Normal View History

\v 6 Wọ́n a máa fẹ́ áwọn àyè pàtàkì ní ibi àsè àti àwọn ibujoko pàtàkì nínú Sínágọ́gù \v 7 Wọ́n sì tún fẹ́ kí a máa kí wọn ní ìkí ẹ̀yẹ nínú ọjà, kí àwọn ènìyàn sí màa pè wọ́n ní 'Rábì.'