\v 6 Wọ́n a máa fẹ́ áwọn àyè pàtàkì ní ibi àsè àti àwọn ibujoko pàtàkì nínú Sínágọ́gù \v 7 Wọ́n sì tún fẹ́ kí a máa kí wọn ní ìkí ẹ̀yẹ nínú ọjà, kí àwọn ènìyàn sí màa pè wọ́n ní Olùkọ́ni.